Òsanyìn, ó jé òrìsà pàtàkì nínú àwon òrìsà tí wòn jo wá sí ayé,
Odù, ifá tí ó rò wá sí ayé ni Òsé-eníwo yí n’lò ro Òsanyìn wá sí òde ìsálayé.
Èsù Òsanyìn yí n là n pè ní Èsù Ìlàré.
Èsù Ìlàré yí ni Èsù ó bá Òsanyìn wa sí òde ìsálayé tó si jé wí pé n ní mòòò ló, tí ó bá rúbò ní odún Èsù Ìlàré ni yíò gbé ebo ré dé esé Olódùmarè ní bùda-ebo.
Òsanyìn ni òrìsà tí ó jé, eni tò jé olóríi
Ajáwé-wagbò soògùn, ó si jé molé tó se pé gbogbo òun tí àwon molé yòó kú mò se fún omo won àti aráyé gbogbo n lòun náà mòo se.
Èsù Ìlàré ni Èsù Òsanyìn tí ò wà fún Òsanyìn ní òde Ìsàlayé.
Osanyin é um importante orixá dentre aqueles que vieram juntos ao mundo. O odu de Ifá que o acompanhou ao mundo é Òsé-eníwo.
O Exu de Osanyin é chamado Exu Ìlàré, ele o acompanhou ao aiê. Quando Osanyin está fazendo as oferendas, ele precisa da ajuda de seu Exu. Exu Ìlàré carrega suas oferendas até Olodumarê, no lugar apropriado, onde as oferendas são aceitas.
Osanyin é a cabeça de Ajáwé-wagbò soògùn, o herbalista entre os orixás. Ele é um imalé cuja conduta é semelhante à dos outros imalés. Ele concede seu auxílio às criaturas e aos povos do mundo. Exú ìlàré é o Exu de Osanyin.
FRAGMENTO RETIRADO DO TEXTO DE IFÁ, RECITADO PELO BABALAWO IFATOOGUN, DE ILOBU, NIGÉRIA.
O TEXTO NA INTEGRA ENCONTRA-SE NO LIVRO: ÈSÙ. JUANA ELBEIN DOS SANTOS E DEOSCOREDES MAXIMILIANO DOS SANTOS (MESTRE DIDI ASIPA)- SALVADOR; CORRUPIO, 168p, 2014.