Posts Tagged With: Adura

ADURA OSANYIN

ADURA OSANYIN   Esinsin abedo kinnikinni, Akepe nigba oran, Elese kan ju elese meji, Ewe gbogbo kiki oogun, Ewe a je, oogun a je fun mi, Loni emi fe ire re, Osanyin jowo fun mi nire, Fun mi ni ola, Wa wo mi san, Ki o si fun mi ni aabo, oro ati alafia.   … Continue reading »

Categories: Ossayin, Reza, Tradição Africana | Tags: , | 2 Comments